Home iroyin Paga! Iku pa Otun Balogun Olubadan!
iroyin - August 25, 2017

Paga! Iku pa Otun Balogun Olubadan!

Lasiko ti ilu Ibadan si n wa ona lati yanju awuyewuye to n sele lori awon oba miiran ti ijoba Ipinle Oyo fe gbe dide, okan lara awon oloye pataki ilu naa ti je Olorun nipe o.

Oloye naa ni Otun Balogun Olubadan, Dokita Femi Olaifa, eni ti a gbo pe o di oloogbe ne owuro oni.

Osibitu UCH ni a gbo pe oloye naa dake si.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…