Ambode bere si ta apo iresi odun ni N12,000
Iroyin ayo tun ti de si Ioinle Eko bayii o, tori ijoba Akinwunmi Ambode tun ti ko iresi Lake Rice wolu.
A gbo pe iresi to je egberun lona meta apo (3000 bags) ni o wa nile fun tita bayii, lati je ki odun Ileya to n bo yi sokutu-wowo..
Nigba ti awon oloja miiran n ta apo iresi ni owo to to egberun mejidinlogun (N18,000), egberun mejila (N12,000) ni Ambode n ta tie, ti apo kekere si je egberun mefa.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…