Yokolu, yokolu, Ronaldo da Messi mole. O gba UEFA Best Player of the Year
Apere ohun ti yoo sele ninu idije World Player of the Year ti yii ti fara han bayii o, nipe pe Christine Ronaldo ni won mu ni UEFA Best Player of the Year fun ti odun yii.
Ronaldo jan Lionel Messi ati Gianluigi Buffon mole lati gba ife eye naa.
Eekererin ti Ronaldo yoo gba koobu naa niyi.
Opo eniyan lo gba pe odun to lo ko dara to fun Messi, paapaa ti Barcelona ko gba ife eye Liigi ati Champions Cup.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…