Remi Surutu ba Eucharia kedun lori iku omo e
Osere fiimu ti a mo si Remi Surutu, ti ba akegbe re lede oyinbo, Eucharia Anunobi, kedun iku omo re.
Se eni ti nnkan bas se ri, yoo mo bi o se n ri lara elomiran.
Surutu naa ti padanu omo ni nnkan bii osu meta seyin, to si je pea run arunmoleegun o pa omo re naa lo pa omo Echaria, ti oruko re n je Raymond.
O ni oun ba Eucharia daro gidi. O fi kun un pe oun mo pe obinrin naa sa ipa re lori Raymond, sugbon ti Eledaa lase.
Surutu was gbadura ki Olorun durob ti Eucharia.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…