Home iroyin Iku b’ola je! Oni ni MKO Abiola ko ba pe ogorin odun laye
iroyin - August 24, 2017

Iku b’ola je! Oni ni MKO Abiola ko ba pe ogorin odun laye

 

Aseje nla ko ba sele ni orile-ede yii lonii, to ba je pe iku ko bola je ni 1998 ni, nipa bi o se pa Oloye MKO Abiola.

Ohun ti ko ba fa aseje naa ni  pe oni ni ko ba pe eni ogorin odun laye.

Eyi tumo si pe odun bii odun meta ni Ojogbon Wole Soyinka fi ju Abiola lo, nigba ti Oloye Olusegun Obasanjo fi bii odun kan ju u lo.

Ijoba ologun Babangida, Sanni Abacha ati Abdusalami Abubakar lo gbe Abiola si atimole leyin ti awon omo Naijiria ti dibo yan an gege bii Aare ni ojo kejila, osu kefa odun 1993.

Leyin ti Abacha ku, ti Abdusalami de ipo ni Abiola ku iku ojiji, lona ti opo eniyan fi fur ape ejo lowo ninu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…