Èmi kò yájú sí Buhari – Fayose
Gomina ipinle Ekiti, alagba Ayodele Fayose lo n salaye fun awon oniroyin pe oun ko le yaju si agbalagba, awon eniyan ni won si oun gbo. O ni omo Yoruba ni oun, eya to kun fun aponle ati owo.
Foyose ni oun ti oun n so ni pe Buhari ko lagbara fun isoro Naijiria. Ojo ori ati ailera ni oun n salaye fun awon eniyan, arun oju si ni eleyii, ko ki n se ohun to soro lati mo rara.
O ni oun fe ki Buhari lo sinmi pelu iru ojo ori re, ko ye ki o si maa doju ko isoro iru ti orileede yii.
Fayose tun ni ooto wa lara ohun ti awon kan ko fi nifee si oun, o ni se a mo pe etan lo laye. O ni opo eniyan to feyin ke, feyin ke ni ebi n pa kara-kara sugbon ti won ko le so. O ni eyi ni iru oun to sun mo awon ara ilu daadaa mo ti oun ko si le fi si abe ahon rara.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…