Home LÁGBO ÀRÍYÁ E ma f’oku we alaaye, baba mi wa laye, omo Baba Sala figbe bonu
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 24, 2017

E ma f’oku we alaaye, baba mi wa laye, omo Baba Sala figbe bonu

Okan lara awon omo Baba Sala, Emmanuel Olaiya, ti so pe iro funfun balau ni awon to so pe osere apanilerin-n naa ti ku n pa.

Ojo Isegun ni iroyin tan kanle pe Baba Sala ti ku, ti opo eniyan si n daro re.

Emmanuel ni kii se ohun to dara ki won maa paro iku mo eniyan.

O ni nigba ti oun gbo pe baba oun papoda, oun gbe foonu re, oun pe e , o si dahun lohun terin-teye.

Koda o ni Baba Sala n bu okele lowo nigba naa ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…