Shina Peller gbé Alaafin, Ọọni, Wasiu Ayinde lọ sí Ìsẹ́yìn
Ero ko gba ese laipe yii nigba ti asekagba idije ere boolu ti okan lara awon baba onimajiiki, Professor Peller, da sile.
Irepo United ati Saki West Rovers ni won dije lojo naa.
Lara awon to pese sibe ni Alaafin ti Oyo, Oba Lamidi Adeyemi, ati Ooni ti Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi, nigba ti Aseyin ti Iseyin, Oba Abdulganiyu Salau, wa nikale.
Awon akorin pataki bii Wasiu Ayinde, Davido, Sound Sultan, 9ice, Small Doctor, CDQ, Eniola Badmus, Taye Currency, Skiibi, Terry Apala, Baseone ati Juniorboy Que Peller wa nibe.
Iseyin United lo gbegbe oroke lojo naa.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…