Ọ̀rọ̀ bẹ́yìn yọ, Barcelona gbé Neymar lọ sí kóòtù
Aawo to wa laarin Barcelona ati Neymar ti ba ibomiran yo, nip ape egbe agbaboolu naa ti gbe omokunrin naa lo si ile ejo.
Neymar ja ara re gba pati lowo Barca ni nnkan bi osu kan seyin, nigba to darapo mo PSG, egbe agbao da buruku owo lu u.
Igba milionu poun o le meji-lelogun (222 million pounds ni PSG da le Neymar lori.
Barca so lojo Isegun pe Neymar ko tele adehun ti awon ni pelu re nigba ti awon fe gba a. Nipa bee, won gbe lo sile ejo pe o gbodo san milionu mejo poun o le die fun awon.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…