O se, omo Eucharia Anunobi di oloogbe
Inu ibanuje nla ni osere Nollywood, Eucharia Anunobi, wa bayii o, tori omokunrin re kan soso ti di oloogbe.
Opo eniyan lo n ba a kedun latari isele yii.
Osere fiimu pataki ni Eucharia tele, to to wa di ojise Olorun.
A o maa fi hulehule iroyin yii to yin leti.
Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo
Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …