Home Orisirisi Àtúntò lọ́ba-lọ́ba: Olubadan fẹ́ bá Ajimobi fa surutu
Orisirisi - August 23, 2017

Àtúntò lọ́ba-lọ́ba: Olubadan fẹ́ bá Ajimobi fa surutu

Olubadan ti Ibadan, Oba Saliu Adetunji, ti so pe oun ko fara mo igbese ti Gomina Ipinle Oyo, Senito Isiaka Ajimobi, gbe nipa gbigbe awon oba mejilelogbon miiran dide ni agbegbe Ibadan.

Olubadan so ninu atejade kan pe ohun ti Gomina naa n se ko ba asa ati itan lobaloba Ibadan mu.

O ni kii se ise gomina lati maa gbe oba miiran dide.

O ni bi idi kan ba tile wa lati se bee, Igbimo Olubadan ati awon Ijoye re lo ye ko se eto naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…