Ẹ gbani, ẹ làjà! Eku ti fẹ́ẹ jẹ ọ́fíìsì Buhari tán
Eni to ba n ta oogun eku ti won n pe ni otapiapia bayii, to ba koja lo si Abuja, afaimo ni ko ma di olowo ojiji.
Idi ni pe to ba ri aaye de ile ijoba nla ti a mo si Aso Rock, o seese ki awon alase ibe ra oja re ni iyekiye to bad a lee.
Eredi akawe yii ni pe Akowe Iroyin fun Aare Muhammadu Buhari, Ogbeni Garba Sheu, ti so pe eku ti je oofisi Aare Muhammadu Buhari putuputu.
Garba so fun awon oniroyin lonii pe wahala ti awon eku laabi naa da sile lo fa a ti Buhari ko fit ii maa lo oofisi naa, to si je pe ile re lo ti n sise.
Isele naa ti wa n ya opo eniyan lenu bayii, tori won ko mo tele pe eku wa ni Aso Rock naa.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…