Home LÁGBO ÀRÍYÁ Aboyúnmosù-má-mọjọ́: Benita ti di abara méjì – gẹ́gẹ́ bíi Funke Akindele
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 22, 2017

Aboyúnmosù-má-mọjọ́: Benita ti di abara méjì – gẹ́gẹ́ bíi Funke Akindele

 

Ope o! Osere to je omode irawo nigba kan, Benita Okojie, naa ti di abara meji o. Odun to lo ni Benita se igbeyawo pelu arakunrin kan ti o n je Olawale, ti ife won si loyin to ladun.

Olorun ti wa fi oba le e fun won, pelu bi O se yonda oyun fun omobinrin naa.

Bakan naa, ana ni IROYIN OWURO gbe e jade pe osere fiimu, Funke Akindele, naa ti di abara meji.

Baale re, Abdurasheed Bello, naa ni Olorun fi ise iyanu naa ran.

Ki Edumare so awon mejeeji layo ati alaafia. Ka gbo’hun iya, ka gbo’hun omo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…