Home Orisirisi ‘Wọn kò jẹ́ kí Olori Wuwaola gbé bẹ́ẹ̀dì kúrò ní ààfin Ọọni’
Orisirisi - August 21, 2017

‘Wọn kò jẹ́ kí Olori Wuwaola gbé bẹ́ẹ̀dì kúrò ní ààfin Ọọni’

Bi o tile je pe Ooni ti Ile-Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi, ko tii so oro kan gbogi lori ija ti won ni o be sile laarin oun ati Olori Wuraola Ogunwusi, awon ore ayaba naa ti so pe o ti ko kuro ni aafin.

Won ni obinrin naa ko ri igbadun je to nigba to wa nibe.

Gege bi akoroyin Kemi Ashefon se so lori iwe iroyin alatagba re,  awon ore Wuraola so pe lojo to fe ko jade kuro ni aafin, awon kan ko je ko mu nnkan kan jade.

Won ni o fe gbe beedi nla tuntun kan to sese se, sugbon won ko gba a laaye.

Sugbon sa o, ohun ti a gbo gbeyin lati Aaafin nip e ko si ija kankan laarin awon ololufe nla meji naa.

Lose to lo ni akowe iroyin Ooni, Ogbeni Moses Olafare, so pe iro ni awon to so pe ija wa nile n pa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…