Home Orisirisi Ọpẹ́ o, ikùn Funke Akindele ti ń taari síta. Aboyúnmosù-má-mọjọ́!
Orisirisi - August 21, 2017

Ọpẹ́ o, ikùn Funke Akindele ti ń taari síta. Aboyúnmosù-má-mọjọ́!

Yinkin ni inu awon ololufe Funke Akindele yoo maa dun bayii ti won ba ri awon foto re kan to sese ya.

Ikun re to ri pelebe tele ti n yo sita, leyii to toka si pe isu ti Olorun gbin sibe lo n ta jade.

Lasiko eto kan ti awon Globacom se, nibi ti Funke ti wo sueta ti ko se gbagere ni won ti ya foto naa.

Idunnu nla ni eyi maa je fun Funke ati baale re, Abdurasheed Bello, tori yoo tumo sip e Olorun ti da won lare; O ti gbe won leke awon alasotele ibi to so pe lapalapa ko ni bimo ninu igbeyawo won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…