Èrò pitumu lẹ́yìn Buhari, ẹ wo fídíò náà nísàlẹ̀ …
Iyalenu ni ero to pade Aare Mohammadu Buhari je fun opo eniyan ni orileede Naijiria. Ero ti ko mo niwonba lo ro tele moto Aare, oro naa tun dabi igba ti o sese de ori aleefa tabi igba to n se iponlongo ibo. (Sai Baba!)…
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…