Home iroyin Buhari kò setán láti yọ mínísítà kankan dànù
iroyin - August 21, 2017

Buhari kò setán láti yọ mínísítà kankan dànù

Opo eniyan to n reti pe Aare Muhammadu Buhari yoo se atunto ijoba re ni lati wa ibi kan jokoo sin a o, tori Buhari ko menu ba ohun to jo eleyii ninu oro to baa won omo Naijiria so ni owuro yii.

Awon kan ti n ro pe Buhari yoo yo awon alabasise re kan to je pe a ko ri nnkan kan ti won n se pato.

Dipo eleyii, ninu oro to baa won eniyan so leyin to ti lo osu meta o le die ni London, nibi to ti n gba iwosan, Buhari so oro ibinu si awon ti won ni awon fey a kuro ni Naijiria, paapaa awon Biafra tuntun ti Kanu Nnamdi solori fun.

Bakan naa, o ni ijoba oun yoo tubo gbogun ti Biafra.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…