Home ÀRÒJINLẸ̀ Àfi kí Elédùà máa sọ́ wa pẹ̀lú oúnjẹ òkè òkun, ẹ wo fídíò yí
ÀRÒJINLẸ̀ - August 21, 2017

Àfi kí Elédùà máa sọ́ wa pẹ̀lú oúnjẹ òkè òkun, ẹ wo fídíò yí

A ni lati maa sora, ki a si kun fun adura pelu awon orisii ounje ti won n ko wole lati ile okeere. Awon ounje buruku yii lo n fa awon aisan orisiirisii ti a ko gbo ri ni ile wa.

Bi awon ika eniyan se n ko nnkan sinu eja ni won n ko sinu adiye bee naa ni won tun n ge ora fun wa bii iresi. E wo fidio yii…

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…