Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Ọmọ Nàìjíríà kán kú lójijì nítorí Arsenal
ERÉ ÌDÁRAYÁ - August 20, 2017

Ọmọ Nàìjíríà kán kú lójijì nítorí Arsenal

 

 

Isele buruku kan se ni Anara, ni Ipinle Imo, lojo Satide, nigba ti omo Naijiria kan, Dominic Ejembi, subu lule, to si ku nigba ti won gba ami ayo wole Arsenal.

Isele naa se nigba ti egbe agbaboolu Stoke ju awon sile Arsenal. Ilu oyinbo ti awon egbe agbaboolu mejeeji wa ni won ti n gba boolu naa, ti Dominic si n wo o ni Anara, ni ile iworan ti won n pe ni viewing centre.

Okunrin kan ti isele naa soju re, iyen Chuks Amaku, lo so oro yii di mimo.

O ni kete ti ami ayo wole Arsenal ni Domminic subu lule, to si je Olorun nipe ki won to gbe e de osibitu.

Chuks ni eni kan to nifee Arsenal de gongo ni oloogbe naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…