Home LÁGBO ÀRÍYÁ O PELEMỌ! Ibrahim Chatter wọ pátá lásán nínú fíìmù tuntun!
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 20, 2017

O PELEMỌ! Ibrahim Chatter wọ pátá lásán nínú fíìmù tuntun!

O PELEMO! Ibrahim Chatter wo pata lasan ninu fiimu tuntun!
Yoruba bo, won  ni ona ofun, ona orun. Ati pe ise ti eniyan ba nifee si, ko si ibi ti eniyan ko le se e de
Eyi lo difa fun gbajumo osere Ibrahim Chatter to fi wo panti lasan ninu fiimu kan to sese n  se.
Ibrahim Cjatter je osere tiata kan ti ori re pe pupo.
Ko si iru ipa to ko le ko daadaa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…