Eré àsápajúdé: Mọ́tò tàkìtì lẹ́ẹ̀mẹwàá
Ere asapajude ran arakunrin kan lo si orun osan gangan lojo Satide nigba ti moto Toyota to n wa takiti leemewaa.
A gbo pe gbogbo awon ero to ko lo fara pa yannayanna.
Oju ona Gboko si Maiduguri ni isele laabi naa ti se.
Awon amoye maa n se kilokilo pe ki a ye sa ere asaju tori a ko mo ohun ti o le sele lairoti.
A gbo pe moto naa jalu galoobu ni.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…