Ológìnní Buhari tàjò dé
Aare Naijiria, Mohammadu Buhari ti aisan ti gbe lo si ilu London lati bii ojo mejilelogorun-un lo ti wolu bayii. Dide Buhari ti je ki gbogbo eniyan maa ko ha, ha, ha. Buhari seleri lati ba omo Naijiria soro ni ojo Monde gege bi Alhaji Lai Mohammed se salaye fun awon oniroyin nigba to gbalejo re tan.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…