Home Orisirisi Oju wo ni Fayose yo fi wo Buhari lojo ipade igbimo
Orisirisi - August 19, 2017

Oju wo ni Fayose yo fi wo Buhari lojo ipade igbimo

Opo eniyan lo n fi Gomina Ipinle Ekiti, Ogbeni Ayo Fayose, se yeye bayii o.
Eyi da lori ipadabo Aare Muhammadu Buhari, eni to wolu Abuja lonii, leyin to ti gba iwosan fun osu meta o le die ni ilu London.
Nigba to wa nibe, awon eniyan kan so pe o ti ku. Awon kan ni aare to n se e ti so di efo tete, won ni ori aga alaare lo wa.
Lara won ni Fayose, to so asofowosoya pe omi ti tan leyin eja Buhari.
Lati osan ti Aare ti wolu ni opo eniyan ti n wenu si Fayose lara; paapaa, won ni o ye ko ti pokunso, tori o so pe ti Buhari ba pada wale oun yoo se bee.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Kò sí nǹkan tó ṣòro tó kí ènìyàn pàdánù ọkọ….. Bimbo Oshin

Kò sí nǹkan tó ṣòro tó kí ènìyàn pàdánù ọkọ….. Bimbo Oshin Ọrẹ Òtítọ́jù Iná ọkọ,aya …