Home LÁGBO ÀRÍYÁ Iyawo Seun Egbagbe n woju Olorun lori baale re to wa ni atimole
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 19, 2017

Iyawo Seun Egbagbe n woju Olorun lori baale re to wa ni atimole

Bi opo eniyan ba tile gbagbe fun onise ariya ti oruko re n je Seun Egbagbe wa ni atimole, iyawo re, eni to bimo fun un, Oyenike, ko ma gbagbe.

O ti fee to odun kan bayii ti Egbagbe ti wa ni atimo lori esun pe o lu jibiti leralera.

Ile ejo ti fe gba beeli Egbagbe, sugbon awon molebi re ko ri ohun ti adajo ni ki won mu wa.

Oyenike gbe foto oun ati omo re jade, nibi ti won jokoo si, ti won n woju Olorun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…