Ayé jíjẹ gba ọgbọ́n
Ogbon ni gbogbo nnkan gba nile aye yii. E wo arakunrin yii bo se n yo aye je. Ko gberaga rara.O si n daabo bo ara re ni ibi ti agbara re mo.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…