Home Orisirisi Afori, aforun: Dangote f era Arsena. O l’oun maa le Wenger danu
Orisirisi - August 18, 2017

Afori, aforun: Dangote f era Arsena. O l’oun maa le Wenger danu

Baba Olowo Naijiria, Alhaji Aliko Dangote, ko tii jami lori erongba re lati ra egbe agbabolu Arsenal o.

O jo pe igbin tenu mogi o gun un ni Dangote fe se oro naa.

O ni ni kete ti oun ba ti pari ile ise ti won ti n f’opo, iyen refinery, eyi ti o n ko si ipinle Eko, ni oun yoo ra Arsenal.

Sugbon sa o, o ni oun maa le Assen Wenger danu bi eeku ida ba ti te oun lowo.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…