Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ọpẹ́ o! Ọlọ́run ré ẹ̀wọ̀n kúrò lọ́rùn Dammy Kraine
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 17, 2017

Ọpẹ́ o! Ọlọ́run ré ẹ̀wọ̀n kúrò lọ́rùn Dammy Kraine

Baba ati iya akorin igbalode Dammy Kraine gbodo maa yi nile pelu idunnu bayii ni, tori Olorun ti yo ajaga nla kuro lorun omo won.

Dammy Kraine, to maa n da fuji po mo hip hop, ti wa ni ilu oyinbo lati ose bii meloo, nibi to ti n koju ejo esun jibiti ti awon olopaa Amerika fi kan an.

Won ni o lo kaadi ayederu lati ra iwe tikeeti baluu to few o ni Amerika.

Won gbe e si atimole, ti won sig be e lo si ile ejo leyin o reyin.

Sugbon bayii, awon adajo ti ni ko maa pada bo si Naijiria lalaafia. Won ni ko jebi oro naa rara, ati pe akoba adaba ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…