Home Orisirisi N kò lè tíì sọ ẹni tí mo bímọ fún, sùgbọ́n kìí ṣe Odunlade Adekola – Bukola Adeeyo
Orisirisi - August 17, 2017

N kò lè tíì sọ ẹni tí mo bímọ fún, sùgbọ́n kìí ṣe Odunlade Adekola – Bukola Adeeyo

Osere fiimu to sese n goke agba, Bukola Adeeyo, ti pariwo sita pe ko si oro loko-laya laarin oun ati agba osere Odunlade Adekola o.

Aipe yii ni Olorun fi omo lanti-lanti jinki Bukola, sugbon awon eeyan kan ni Odunlade lo bi omo naa fun.

Oro naa ti n ja rain-rain nile fun ose meloo kan.

Won ni wole-wode ti wa laarin awon osere mejeeji ki oyun to de.

Ohun to tun mu ifura lowo ni pe a ko tii mo okunrin ti Bukola bimo fun gan-an.

Bee, oun naa ni oun ko tii etan lati fi oju okunrin naa han.

Ni nnkan bii ojo meji seyin, Odunlade naa ni oun ko ni oro kankan lati so lori isele naa. O ni ohun to ba wu onikaluku lo le maa fie nu re so.

Bukola ni ise fiimu nikan lo da awon po. O ni oga oun ni Odunlade je.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…