Home iroyin Ẹ̀yà ara ènìyàn nínú Sọ́ọ̀sì, kín ló dé?
iroyin - August 17, 2017

Ẹ̀yà ara ènìyàn nínú Sọ́ọ̀sì, kín ló dé?

Owo awon olopaa ipinle Ogun ti te Pasito Samuel Babatunde, omo odun metadinlogorin (77years) ni ilu Ota, ipinle Ogun ni oni. Eya ara eniyan lorisiirisii ni won ri mole si ile ijosin naa.

Oga olopaa ni ipinle Ogun, ogbeni Ahmed Iliyasu fidi re mule, o ni yato fun Pasito ijo naa, owo awon tun te babalawo won, Haruna Afolabi to je omo odun metalelogoji (43years) pelu awon meta miran ti ijoba funra si pe won mo si ise ibi naa.

Pasito Babatunde ni oludasile ile ijosin Cherubu ati Seraphim to wa ni Itedo Isinmi, Ayo Parish, Egan Iyesi ni ipinle Ogun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…