Home Orisirisi Let them say: Olori Ooni Wuraola se bebe ni Sierra Leone
Orisirisi - August 16, 2017

Let them say: Olori Ooni Wuraola se bebe ni Sierra Leone

 

 

Pelu gbogbo ohun ti awon eniyan n so nipa igbeyawo Ooni Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi, ati ayaba, Olori Wuraola, a le maa ro pe ori oronu ni obinrin naa yoo wa.

Kin lo le ba eniyan lokan je ju pe ki ibasepo laarin oun ati Oba pataki bii Ooni?

Sugbon sa o, eni ti won goju okun le ko jo eni aagba.

Olori Wuraola ko tii so nnkan kan lori ohun ti won lo n sele laafin. O jo pe orin LET THEM SAY lo wa lokan re.

O jo pe ipa ti won n pose, ara lo fi n san.

Dipo ki Olori Wuraola o kawo gbera, ise aanu lo si n se kaakiri.

Gege bi o ti so lori ero alatagba, o sese se ise aanu lo si orile-ede Saro ni, nibi ti ile ti ya pa opolopo eniyan.

O ni ile to le gba aadota eniyan ni oun sese fun awon ti ajalu naa so di alainile.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…