Home Orisirisi Iro ni won pa, ko sija kankan laarin emi ati Olori – Ooni
Orisirisi - August 16, 2017

Iro ni won pa, ko sija kankan laarin emi ati Olori – Ooni

 

Iroyin ayo ati ifokanbale ti jade lati Aafin Ooni ti Ile-Ife, Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi, lori wahala ti awon kan koko so pe o be sile laarin oun ati Olori re, Ayaba Wuraola Ogunwusi.

Kabiyesi ni oro ko ri bee. O ni aarin awon si dan moran ati pe oun ko ko iyawo oun sile rara.

Akowe iroyin fun Ooni, Ogbeni Moses Olufare, so pe awon ko mo ibi ti aheso naa ti jade pe Ooni ti ko Olori sile.

O wa ni laipe yii, atejade pataki kan yoo jade lati aafin lori oro naa.

Adura wa nip e Olorun ko ni je ki ile ola o daru o.

Oodua Atewonro a tubo je ki alaafia ati ayo o maa joba ni aafin Ife ati kaakiri ile Yoruba.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…