Àwọn agbébọnrìn ya wọ ófíìsì EFCC
Ajo EFCC ni ajo ijoba to n samojuto awon to ba se owo ilu maku-maku. Awon ni o n gbogun ti awon onijibi, ole ati awon alajebanu miran paapaa julo owo ijoba. Owuro oni ni iroyin kan wa lara pe awon adihamora digun lo si olu ileese ajo naa to wa ni Abuja, won si lo ba awon nnkan je.
Awon agbebonrin naa wa fi leta kan sile lati fi kilo fun awon to n se iwadii nipa owo kikoje daa duro ki won ma baa femi ara won wewu.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…