Àràmàndà! Real Madrid sọ Barcelona di dìndìnrìn lórí pápá
Afaimo ki apadasi buruku ko ma ti ba egbe agbaboolu Barcelona o.
Idi ni pe oun ti ota won Real Madrid n ba won gba lowolowo yii ninu abala keji Super Cup to n lo lowo bayii ko dara.
Won ti ju ami ayo meji ototo sile Barca, ti awon ko si le ta putu.
Bee, ko si Ronaldo lori papa, tori o gba Red Card nigba ti won koko pade.
Nigba ti Real Madrid n gba boolu bi iwin, awon Messi wa n pooyi rai bi eni eyin fo mo ninu.
Abala isinmi, iyen half time, ni won wa bayii.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…