Home Orisirisi Ko je je bee! Wọ́n ní ìjà bẹ́ sílẹ̀ láarin Ọọni àti Olorì Wúràọlá
Orisirisi - August 15, 2017

Ko je je bee! Wọ́n ní ìjà bẹ́ sílẹ̀ láarin Ọọni àti Olorì Wúràọlá

Kayeefi nla lo n se opo eniyan bayii, latari iroyin iruju to n jade  pe ija nla ti be sile laarin Kabiyesi ati iyawo re, iyen Olori Wuraola.

Ni nnkan bii odun kan ati aabo ni won se igbeyawo alarinrin, ti toba tijoye  pe sibe.

A gbo pe o ti to igba die ti nnkan ko ti dan moran mo.

Won ni Olorun nikan lo le yanju oro to wa nile naa.

Opo eniyan, paapaa awon omo Alade, ni yoo maa gbadura pe ki idaru ma sele ni aafin Oba Ogunwusi – ati aafin gbogbo oba Yoruba pata.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…