Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Mo máa kúrò ní Chelsea – Costa
ERÉ ÌDÁRAYÁ - August 14, 2017

Mo máa kúrò ní Chelsea – Costa

Ọdọmode Agbabọọlu daadaa ti gbogbo aye mo si Diego Costa ni o ni oun ni lati kuro ninu egbe agbaboolu Chelsea. O ni oun ni lati lo ibi ti won ba ti n fe oun ti won si n fe bukata oun. O ni lati bi osu karun-un ni manega egbe agbabolu naa, ogbeni Antonio Conte ti pa oun ti bi aso to gbo.

O ni manega ko fe k’oun lo, ko si fe maa lo oun gege bii okan ninu agbaboolu mokanla akoko. Costa ni eleyii ko ni le rogbo nitori pe oun ko kii n se odaran ti won maa ti mole, ti ko ni le rin ko yan si ibi to ba wuu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…