Home iroyin ASUU bẹ̀rẹ̀ ìyansẹ́lódì
iroyin - August 14, 2017

ASUU bẹ̀rẹ̀ ìyansẹ́lódì

Oni ojo Monde ojo kerinla osu kejo odun yii ni awon ajo oluko Fasiti jake-jado Naijiria “ Academic Staff Union of Uniẹersities” (ASUU) bere idasesile. Won ni awon maa wo ise niran titi ti ijoba apapo fi maa da awon lohun.

Won ni o ti su awon lati maa sise bi “Erin ki awon si maa je ije Eliri”. Won tun ni gbogbo ileri ijoba ninu ipade awon ati ijoba ni gbogbo igba ni ko so eso rere fun awon.

Won ni awon ileri alangba ijoba apapo ti su awon. Won ni awon maa mọ ise loju ni titi ti ijoba fi maa ri ti awon ro.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…