Home Orisirisi Baba Adeboye so asiri opa adura to maa n lo
Orisirisi - August 13, 2017

Baba Adeboye so asiri opa adura to maa n lo

 

 

Oludari Agba ni Agbaye fun soosi Redeemed Christial Church of God, Pastor E. A. Adeboye, ti so asiri opa kan to maa n na soke leekokan to ba n gba adura.

Lasiko ipago nla kan to waye ni soosi naa to wa ni Mowe, Adeboye ni Oludasile ijo naa, Alagba Fadayomi, lo fun oun ni opa naa ki o to ku.

O ni ko si adura ti oun fi adura naa gba ti kii gba, bi o tile je pe kii se pe gbogbo igba lo maa n mu opa naa jade.

Opa naa ranni leti opa Mose, eyi ti o maa n lo nigba ti awon omo Isreal ba n wa iyanu, lasiko irin ajo won lati Egypt.

Iroyin ayo to wa fun awon to wa ni ipade to sese pari ni Ridiimu ni pe Baba Adeboye lo opa naa lasiko owaasu re, to si fi gba adura fun won.

 

 

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…