Home iroyin Owo ba Afolabi to n se Yahoo-Yahoo
iroyin - August 12, 2017

Owo ba Afolabi to n se Yahoo-Yahoo

Owo ajo EFCC ti ba okunrin kan ti won pe ni omo ile iwe Osun State Polytechnic, Ire, Afolabi Ojo, to je pe jibiti iru eyi ti won n pe ni Yahoo-Yahoo lo n lu kiri o.

Awon agbofinro ni okunrn naa si oja iro, oja jibiti si ori ero alagbeka, to n lo whatshapp ati Instagrama lati maa gba awon eniyan.

O paro pe oun n taja, sugbon ko ta nnkan kan, o kan n fogbon gbowo lowo won ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…