Ọ̀rọ̀ godo-gànìn: Ọmọ Sẹ́nítọ̀ Ekeremadu ń fi ìdí dárà
Laye ojoun, eewo ni ki eniyan maa wo aso ti k obo idi. Paapaa, awon olomoge kii few o aso ti yoo fi sura ara won sita.
Sugbon igbi aye n yi. Nnkan ti yato gedegede bayii. Aye ti daye ohun ti won n pe ni bikini – iyen aso ko bodi.
Okan lara awon omo Igbakeji Aare Ile Igbimo Asofin Agba (Deputy Senate President) naa, Sylva Ekeremodu, naa ti di onibikini bayii.
Foto re kan to sese gbe jade nibi ti oun ati awon oro re ti n gbafe fi die han ninu sura ara re. Opo eniyan lo n ko ‘Haa!’
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…