Ọmọ UNILAG méjì pàdé ikú gbígbóná nínú òtẹ́ẹ̀lì kan
Omo ile-iwe giga ti University of Lagos meji ni a gbo pe won ti ki iku gbigbona o. Ina ni a gbo pe o jo won ni ajopa ninu oteeli kan ni ilu Eko.
Won pe oruko awon omo naa ni Roli Odogwu ati Linda Elegeonye.
Iroyin fi ye ni pe awon omo mejeeji lo si ode kan ni igboro. Nigba ti ile su won sibe, won pinnu lati sun ni oteeli naa.
Oru ojo naa ni ina seyo ni ile igbafe naa, to si ran de yara ti won sun si.
Won ni won gbe won dilodilo lo si ile iwosan Gbagada General Hospital, sugbon epa ko boro mo.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…