Home iroyin Emeka pa baba re nitori ile
iroyin - August 12, 2017

Emeka pa baba re nitori ile

Arakunrin kan ti oruko re n je Emeka Ogbunihuogu ti wa ni ahamo awon olopaa bayii, latari bi o se sa baba re ni asapa.

Isele naa wa lara laasigbo to n lo kaakiri orile ede yii, nibi ti inu bibi abiju ti n da wahala sile.

Awon onimo ijinle ni ebi ati iponju to n ja kaakiri Naijiria lo je ki opo eniyan maa siwahu.

A gbo pe Emeka ati baba naa n ja si ile, ni omo naa ba sa a ni asapa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…