Home iroyin Ara mi ti yá, Dókítà ló ń dá mi dúró – Buhari
iroyin - August 12, 2017

Ara mi ti yá, Dókítà ló ń dá mi dúró – Buhari

Aare Mohammadu Buhari lo n fi oro ibale okan ranse si gbogbo Naijiria nipa ailera re. O ni saka ni ara oun ti da bayii amo oun ni lati gboran si Dokita lenu ki oun to wale. Aare n salaye yii ni igba ti Lai Mohammed to je Minisita eto iroyin ati asa ko iko oniroyin Aso Rock baa lalejo ni London.

Ara awon to lo se abewo naa ni Arabinrin Abike Dabiri, Sehu Garba, Femi Adesina ati awon miran ti won jo n sise po pelu Aare. Koda won gbe ebun kaadi to ni adura ki ara Aare tete ya ni kia fun Buhari.

Buhari ki gbogbo awon to n dari ijoba lati igba ti ko ti si nile. O ni gbogbo akitiyan won pata ni oun n gbo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…