Àgùnbánirọ̀ di ẹni àwátì
Gbogbo abiamo aye, e ma sun lo o. E ba wa wonu emi lo, ki e ba wa kun fun adura.
Idi adura naa ni bi agunbaniro omobinrin kan, Vera Uloma Ukah, se di eni ti won n wa bayii.
Sapele, ni Ipinle Delta, ni Vera ti n sin ilu re, to si je pe o ti to ojo mesan-an ti won ti n wa a .
Awon ebi re ni sukuu to ti n sinru ilu ti wa ni olude, bee Vera ko wa si ile.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…