Owo ti PSG ko le Neymar ko mogbon dani – Arsen Wenger Baba Ijebu
Adari egbe agbaboolu Arsenal, Arsen Wenger, ti bu enu ate lu egbe agbaboolu Barcelona ati PSG, lori owo gege ti won ta Neymar fun ara won.
Ohun ti ko sele ri ninu ere boolu lagbba ti n ni egbe agbaboolu tiwon, ti won si n ko owo to wu won le agbabool lori.
O ni ti won bad a kinni naa da Arsenal, awon ko le na iru owo buruku bee lori eni kankan..
aye sele nigba ti PSG ra Nemar ni igba milionu poun o le ogun ati meji – 220 million pounds.
Nigba to n se akawe lori isele naa, Wenger, eni ti opo eniyan n pe ni Baba Ijebu tori kii fen a owo pupo lati ra agbaboolu, so pe Barcelna ati PSG ko fi opolo se kinni naa.
O ni Olorun lo mo ohun ti yoo sele lojo iwaju, paapaa ti awon orile-ede tabi ijoba
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…