Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Ofo ni Barcelona mu bo lati oja Liverpool
ERÉ ÌDÁRAYÁ - August 11, 2017

Ofo ni Barcelona mu bo lati oja Liverpool

Gbogbo ipa ti egbe agbaboolu Barcelona sa lati ri die gba lara awon omo egbe agbaboolu Liverpool lo ti ja si otubante bayii.

Ofo lasan, ojo keji oja lo ja si.

Kikuro ti Neymar kuro ni Barca je ki aaye nla kan sofo, eyi ti awon alase Barca fe di lonakona.

Won ko tii mo eni ti yoo maa sise po pelu Messi ati Suarez.

Eni to koko wo Barca loju ju ni Coutinho, ti won fe ko ibinu owo to to aadorun milionu owo poun – 90 million dollars – le lori.

Sugbon adari egbe agbaboolu Barcelona ti wa so pe ati Coutinho o, ati Tinhocou o, oun ko tie ta eni kankan mo.

Bakan naa, egbe agbaboolu ortmund ti ile Germany ti so pe oun ko ta idan irita kan to n je Dembele fun Barca.

Eyi lo fa a ti Barcelona tun fi n wo odo Real Madrid bayii, nibi to ti fe ra Asensio.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…