Mo si maa n ri Fela loju ala – Yeni Kuti
Yeni, to je okan lara awon omo ogbontarigi akorin afro, Fela Anikulapo-Kuti, ti so pe oun si maa n ri baba oun loju oorun.
O ni bi o tile je pe o ti di ogun odun bayii ti baba oun ti ku, o si maa n fi ara ha noun ninu ala.
O ni awon agbaagba ile awon miiran ti ko si laye mo naa maa n fi ara ha noun.
Nigba to n so nipa awon nnkan ti oun fi jo baba oun, o ni oun kii lo si soosi.
Odun 1997 ni Fela di oloogbe, nigba to ni arun kogboogun HIV/AIDS.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…