Home Orisirisi Wasiu Ayinde yombo Tiwa Savage ati Yemi Alade
Orisirisi - August 10, 2017

Wasiu Ayinde yombo Tiwa Savage ati Yemi Alade

Onifuji agba, K1 de Ultitame, ti kan saara si awon obinrin to je akorin.

O ni ipa ti won n ko ninu idagbasoke ise alariya, iyen entertainment industry, ko kere rara.

O ni latari eyi, o ye ki a maa se iranlowo fun won ki won le tubo maa goke agba.

O ni ti a ba wo aseyori awon akorin bii Tiwa Savage ati Yemi Alade, a yoo ri i pe won n lo ebun won daadaa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…