Kasamu Buruji doju ija ko Fayose
Senito Kasamu Buruji ati Gomina Ayodele Fayose n fa surutu lowolowo yii, lori ta ni yoo je adari PDP ni ile Yoruba.
Fayose kii gbo, bee ni Buruji kii gba. Eyi tumo si pe o seese ki ija naa tubo gbona si i.
Lasiko ti won n se ipada awon olori egbe naa, Fayose ni Buruji ko ye ni eni to le gbe egbe gun oke agba.
Buruji naa wa da a lohun, o ni Fayose gan-an ni agba ofifo to maa n pariwo lasan.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…