Home iroyin Aregbesola fori bale fun Ooni
iroyin - August 10, 2017

Aregbesola fori bale fun Ooni

Die lo ku ki Gomina Ipinle Osun, Ogbeni Rauf Aregbesola, dobale gbalaja fun Ooni ti Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi, nigba ti kabiyesi naa se abewo si oofisi re ni Osogbo.

Ooni lo ki Aregbe ku aseinde ti iya re to sese lo sibi agba a re ni.

Omo Ogoji odun o le die ni Ooni, ti Aregbe si je eni ogota odun.

Sugbon nile Yoruba, gbogbo eniyan lo maa n bowo fun ori ade.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…