Home iroyin Àjàalẹ̀ míràn l’Ékòó!
iroyin - August 10, 2017

Àjàalẹ̀ míràn l’Ékòó!

Ijeeta ni owo te awon ajinigbe ti won n lo ajaale kan ni opopona Ijaye si Abule Egba l’Eko. Osan oni ni awon eniyan tun bere si ni da giri-giri ni opopona kan naa to lo si ilu Abeokuta aye atijo. Eyi sele ni gbaju-gbaja ibudoko ti won n pe ni ile Zik, agbegbe Mangoro naa tun ni ibi ti a n wi yii.

Titi di asiko ti a n ko iroyin yajo-yajo yii jo, awon olopaa ri meta ninu won ko lo si bareke won ni Ikeja nigba ti owo te okan miran ni aago merin aabo irole yii, taya ti wa lorun re, awon olopaa si n gbiyanju ati gbaa lowo awon ara ilu. Opolopo aso awotele obinrin ni o tun kunle ni adugbo yii ni ibi ti awon ika yii ti n sose. Ikanra to wa lara awon ara ilu ko je ki a tile bi won pe, se obinrin n je loogun ju okunrin lo ni won se doju le obinrin?

Nitori owo yii naa sa. Ki Eledua ma se je ki a rin arinra.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…